Tèmi Nì Tèmi by Brymo
Tèmi Nì Tèmi by Brymo

Tèmi Nì Tèmi

Brymo * Track #5 On Ésan

Tèmi Nì Tèmi Lyrics

Ife mi dariji mi
Omode n se mi
Afarawe O se temi
Ka daduro ni mo wari
Moti so tele tele ri
Igboro O ma rerin ri
Ijakadi lo mu nise
Karohunwi O bopo sise

Bridge
Bi nba fa wa n'ole
Bi nba tule wan'loro
Bi n duro won ma mere
Bi nba sa wa ni mo kere

Chorus
Aba lo aba bo
B'ohun won ko para won oh
Ohun A ni la n nani
Temi Ni Temi

Verse 2
Awelewa forijimi
Mo lakaka kin to de bi
Riro mede O se temi
Nibi lile la n b'okunrin
Ife re sha lo'n duro timi
O dudu, O funfun, O Pupa
Ife re sha lo'n munu tumi
Ninu erun at'ojo at:ilera

Bridge
Bi nba fa wa n'ole
Bi nba tule wan'loro
Bi n duro won ma mere
Bi nba sa wa ni mo kere

Chorus
Aba lo aba bo
B'ohun won ko para won oh
Ohun A ni la n nani
Temi Ni Temi

Outro
Aba lo aba bo
Temi loje lale eni oh
Gbogbo igba ti o ba lo
Mo mo pe o pada wa

Tèmi Nì Tèmi Q&A

Who wrote Tèmi Nì Tèmi's ?

Tèmi Nì Tèmi was written by Brymo.

Who produced Tèmi Nì Tèmi's ?

Tèmi Nì Tèmi was produced by Mikkyme Joses.

When did Brymo release Tèmi Nì Tèmi?

Brymo released Tèmi Nì Tèmi on Thu Sep 09 2021.

Your Gateway to High-Quality MP3, FLAC and Lyrics
DownloadMP3FLAC.com