Àkọ́kọ́ by Brymo
Àkọ́kọ́ by Brymo

Àkọ́kọ́

Brymo * Track #1 On Ésan

Àkọ́kọ́ Lyrics

Emi ni emi leni na
Okunrin meta at'abo to n forin ko
Emi ni emi lomo na
Okunrin merin at'abo won tenu mo
Mo lanu, mo soro
Mo y'ake, mo fo ro
Omo oloforo, Mo j'akara oforo
Emi ni Ah, Emi ni Oh
Emi ma leni to n so nigboro
Emi ni ya, Emi ni yo
Awon mama gan soro ni popo

Won le mi l'akoko
Won le mi l'akoko oh
Won le mi l'akoko oh
Won le mi l'akoko oh

Emi ni, Okunrin na
T'awon majesi sope o'morin gan
Emi ni, emi lomo na
Gbogbo aradugbo lo n tenu mo
Emi baba olowo
Mo sowo, mo jere
Iwa at'opolo lo n lo
Awon ota ti rupo
Emi ni Ah, Emi ni Oh
Emi ma leni to n so nigboro
Emi ni ya, Emi ni yo
Awon omoge redi ni popo

Won le mi l'akoko (Iwo l'akoko)
Won le mi l'akoko oh (Iwo l'akoko oh )
Won le mi l'akoko oh (Iwo l'akoko)
Won le mi l'akoko oh (Iwo l'akoko)
Won le mi l'akoko (Iwo l'akoko)
Won le mi l'akoko oh (Iwo l'akoko oh )
Won le mi l'akoko oh (Iwo l'akoko)
Won le mi l'akoko oh (Iwo l'akoko)

Àkọ́kọ́ Q&A

Who wrote Àkọ́kọ́'s ?

Àkọ́kọ́ was written by Brymo.

Who produced Àkọ́kọ́'s ?

Àkọ́kọ́ was produced by Mikkyme Joses.

When did Brymo release Àkọ́kọ́?

Brymo released Àkọ́kọ́ on Thu Sep 09 2021.

Your Gateway to High-Quality MP3, FLAC and Lyrics
DownloadMP3FLAC.com