Eyin Agba by Musiliu Haruna Ishola
Eyin Agba by Musiliu Haruna Ishola

Eyin Agba

Musiliu Haruna Ishola * Track #5 On Soyoyo

The music player is only available for users with at least 1,000 points.

Eyin Agba Lyrics

[Intro]
Mo ti wa ri b'aye kin to t'ile wa
Mo ti ṣe'ba l'odo àwọn agba o
Ẹyin agba, e je o tuwa ṣe

[Chorus]
Eyin agba o, o-ay
Eyin agba t'e ba ri pe a ṣe yín
E ma ro'jo wa s'ibi t'o ṣoro ọmọ yin l'aje ogbon o de bi kan
Ọmọ yin l'aje ogbon o de bi kan (Ọmọ yin l'aje ogbon o de bi kan)
Eyin agba o, o-ay
Eyin agba t'e ba ri pe a ṣe yín
E ma ro'jo wa s'ibi t'o ṣoro ọmọ yin l'aje ogbon o de bi kan

[Verse]
Gatikule, gatikule
Àti t'eba s'inu ṣáko maja, ogberi to ma je ma ni nkan
Egunjobi Ishola o, iyi t'oba Olúwa fún e ko ni pare l'aye
E ṣ'amin kin gbó
Egunjobi Ishola o, iyi t'oba Olúwa fún e ko ni pare l'aye
E ṣ'amin kin gbó
Ọ̀tá kan bínú lásán, wọn o lè r'ana gbẹ gba, Oba t'o ṣ'oni bo wa ṣ'ola
Ao ni di ako bata l'àwùjọ olórin

Eyin Agba Q&A

Who wrote Eyin Agba's ?

Eyin Agba was written by Musiliu Haruna Ishola.

When did Musiliu Haruna Ishola release Eyin Agba?

Musiliu Haruna Ishola released Eyin Agba on Fri Jun 16 2000.

Your Gateway to High-Quality MP3, FLAC and Lyrics
DownloadMP3FLAC.com