Ise Oluwa Ko Seni Toye by Musiliu Haruna Ishola
Ise Oluwa Ko Seni Toye by Musiliu Haruna Ishola

Ise Oluwa Ko Seni Toye

Musiliu Haruna Ishola * Track #1 On Soyoyo

The music player is only available for users with at least 1,000 points.

Ise Oluwa Ko Seni Toye Lyrics

[Verse 1]
Ìṣe Olúwa ko s'ẹni tó ye, ìṣe Olúwa ju t'Alfa lo
Ìṣe Olúwa ko s'ẹni tó ye, ìṣe Olúwa ju t'Alfa lo
L'Ọlọ́run ọba fi gbé wa ga
L'Ọlọ́run ọba fi gbé wa ga o, le fi n binu, le fi pegan o

[Verse 2]
Musiliu Babatunde
President fún àwọn al'Apala kari Naija pata-pata
B'a pe olórí, b'olórí n je
Olórí kankan o gbọ́dọ̀ f'ohun torí pe, olórí ju olórí lo
B'a pe olórí, b'olórí n je
Olórí kankan o gbọ́dọ̀ f'ohun torí pe, olórí ju olórí lo
Musiliu Ishola, l'asiwaju yín, ni bi ka kọrin apala to f'ọgbọ́n yo o
E lo meshi onu yín gbogbo yín o, e lo gb'ẹnu dake

[Verse 3]
Ba Tunde Ishola o, ọmọ egungun jobi
B'orin ba dùn, bi o dun, ẹni gbó wo lo mi a wi
Àwa ní bàbà e yẹ ma ṣ'agídí
B'orin ba dùn, bi o dun, ẹni gbó wo lo mi a wi
Àwa ní bàbà e yẹ ma ṣ'agídí
Ka kọrin tó da, Ishola ni asiwaju
Orin tó f'ọgbọ́n yọ, Ishola ni asiwaju
Orin gidi, Ishola ni asiwaju
Musiliu, ọmọ egungun jobi

Ise Oluwa Ko Seni Toye Q&A

Who wrote Ise Oluwa Ko Seni Toye's ?

Ise Oluwa Ko Seni Toye was written by Musiliu Haruna Ishola.

When did Musiliu Haruna Ishola release Ise Oluwa Ko Seni Toye?

Musiliu Haruna Ishola released Ise Oluwa Ko Seni Toye on Fri Jun 16 2000.

Your Gateway to High-Quality MP3, FLAC and Lyrics
DownloadMP3FLAC.com