[Intro: Chief Dr. Sikiru Ayinde Barrister (MFR) & Barry Jhay]
Ẹ ma ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro
Ọrọ mi d'akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu
Koda, ko ṣe China t'ọn gbe ti n jẹ wọn
Ẹni j'alangba n tutu, a kó warapa
Oh-ah, oh-ah-ah-ah
Yeah, ay-ya-ay, ah-ah, ah
Oh-wa, oh, wa-wa-wa
(Nobody's perfect, nobody's perfect)
[Verse 1]
Ye, k'iku ma-ma pa awọn to gbe mi s'ori bi gele
Ki ibanujẹ jina si wa rere, tefe-tefe
K'iku ma p'ọta mi, kan le r'iran wo
(O ri mo fa to n jo, ele no be zobo, different is there, ah)
Ki'ku ma p'ọta mi, kan le r'iran wo
(Mo ṣi n m'ẹyẹ bọ lapo, jẹ gbese Lapo, ọta mi lo n jẹ gbese, wọn mo wassup)
[Pre-Chorus]
If I see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
Motivation gan ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko ni yọ (Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko ni yọ)
[Chorus]
See me, see God o
Abi emi naa kọ? Ọmọde ana, ti wèrè bọ, gentle boy
Yeah-yeah
Ṣe you dey see level o?
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, o yẹ k'eti mọ
[Verse 2]
Ye, as I dey find wetin I go chop, ooh-iy
Make I no jam wetin go chop me
Olúwa lo gbe (Yea-yea), lo gbe mi s'oke
Emi ko le ṣ'ai ṣope
[Chorus]
See me, see God o
Abi emi naa kọ? Ọmọde ana, ti wèrè bọ, gentle boy
Yeah-yeah
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, o yẹ k' eti mọ (Yeah)
Yeah, o l'oju ọmọ t'o damọ
[Pre-Chorus]
If I see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
Motivation gan ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko ni yọ (Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko ni yọ)
[Chorus]
See me, see God o
Abi emi naa kọ? Ọmọde ana, ti wèrè bọ, gentle boy
Yeah-yeah
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, o yẹ k'eti mọ (Yeah)
Yeah, o l'oju ọmọ t'o damọ
[Outro]
Sunshine
See Me See god (SMSG) was written by Barry Jhay.
See Me See god (SMSG) was produced by Dibs.
Barry Jhay released See Me See god (SMSG) on Thu Apr 10 2025.