Iya Alariya by 9ice
Iya Alariya by 9ice

Iya Alariya

9ice * Track #5 On Versus

Download "Iya Alariya"

Iya Alariya by 9ice

Performed by
9ice
About

Iya Alariya is a song by Nigerian indigenous artist 9ice. It was released as the 5th track on 9ice’s 4th studio album Versus: The Battle Line Is Drawn, where he “versed” other artists and made a song together. This song was supposed to be vs. King Sunny Ade, but word was he was too busy. This song h...

Read more ⇣

Iya Alariya Lyrics

[Chorus]
Emi ni kan kan mowa
Moni baba ni igbejo
Mo wowo ra
Mo gbagbe iyin ola ati egan
Iya alariya ken ken, eh-eh
Iya alariya ken ken, eh-eh
Iya alariya ken ken, ma jo mayo
Iya alariya ken ken, eh-eh

[Verse 1]
Ti moba lo, pelu imo kan
Taabi mo re koja lo, pelu inu kan
Sa dede ni blessing awa si odo mi tori mo gbagbo
Egbegberun subun, lotun losi mi
Nkan kan koni se omo olorun
Okeere opoju temi
Emi ni kankan mowa
Moni baba ni igbejo

[Chorus]
Emi ni kan kan mowa
Moni baba ni igbejo
Mo wowo ra
Mo gbagbe iyin ola ati egan
Iya alariya ken ken, eh-eh
Iya alariya ken ken, eh-eh
Iya alariya ken ken, ma jo mayo
Iya alariya kеn ken, eh-eh

[Verse 2]
Isе owo mi, koni di ibaje
Won tie muruwu muruwu mo mi
Wan ko fe te
Baba ti se ileri, pe ma jaiye mi pe pe pe pe
Atele gbe ese n te ono
Ajoke aiye, asake orun
Koni si mi lono
E ye se inu binu si mi ma
Mo ni baba ni igbejo

[Chorus]
Emi ni kan kan mowa
Moni baba ni igbejo
Mo wowo ra
Mo gbagbe iyin ola ati egan
Iya alariya ken ken, eh-eh
Iya alariya ken ken, eh-eh
Iya alariya ken ken, ma jo mayo
Iya alariya ken ken, eh-eh

Iya Alariya Q&A

Who wrote Iya Alariya's ?

Iya Alariya was written by 9ice & King Sunny Adé.

Your Gateway to High-Quality MP3, FLAC and Lyrics
DownloadMP3FLAC.com