Ife by Reminisce
Ife by Reminisce

Ife

Reminisce * Track #10 On Alaga Ibile

Ife Lyrics

[Intro]
Oriye
Reminisce in the building, hehe
Jospo
E le y'ato
Oriye
M'ori mi wu
Ife e

[Chorus]
Ife, ife
Ife, ife
Ife, ife
Ife, ife

[Verse 1]
Ife re lo n m’ori mi wu
Ma je ki ife ko mi l’ominu
Omoge eleyin ju ege
Let me love you jeje
Ni nu ojo, ni nu erun
For better for poorer ni
Baby I go love you, love you
Ma shey ba mi wi

[Pre-Chorus]
Moti lowo lowo (ahan)
Mo ma nawo fun e (ahan)
A ma kolemole (ahan)
A ma bimolеmo (ahn)
Bimolemo fun mi

[Chorus]
Ife, ife
Ifе, ife
Ife, ife
Ife, ife

[Verse 2]
Ogwagigebuyi e mo
Achoronunrungi
As God don butter my bread o
Achorofungi baby
Baby, baby
Majekowo jo naa
Baby o, baby
Maje ki ife la naa

[Pre-Chorus]
Moti lowo lowo (ahan)
Mo ma nawo fun e (ahan)
A ma kolemole (ahan)
A ma bimolemo (ahn)
Bimolemo fun mi

[Chorus]
Ife, ife
Ife, ife
Ife, ife
Ife, ife

[Verse 3]
Hey baby, omo pe mo love e
Titi lailai I can't get enough e
Iwo lakara mi, emi ni puff puff e
Mi o le ever place anyone above e
Awon bobo po nle tanfe snatch e
Awon yoyo yapa tanle match e
Nkan t’oju miri kin toh catch e
Ti ife wa ba dalu, a ma pass e

[Pre-Chorus]
Moti lowo lowo (ahan)
Mo ma nawo fun e (ahan)
A ma kolemole (ahan)
A ma bimolemo (ahn)
Bimolemo fun mi

[Chorus]
Ife, ife
Ife, ife
Ife, ife
Ife, ife
Ife, ife
Ife, ife
Ife, ife
Ife, ife

Ife Q&A

Who wrote Ife's ?

Ife was written by Reminisce.

Who produced Ife's ?

Ife was produced by Jospo.

Your Gateway to High-Quality MP3, FLAC and Lyrics
DownloadMP3FLAC.com