Apala Disco (Presidential Remix) by DJ Tunez (Ft. Musiliu Haruna Ishola & Terry Apala)
Apala Disco (Presidential Remix) by DJ Tunez (Ft. Musiliu Haruna Ishola & Terry Apala)

Apala Disco (Presidential Remix)

DJ TUNEZ & Terry Apala & Musiliu Haruna Ishola

The music player is only available for users with at least 1,000 points.

Download "Apala Disco (Presidential Remix)"

Apala Disco (Presidential Remix) by DJ Tunez (Ft. Musiliu Haruna Ishola & Terry Apala)

Release Date
Fri Feb 16 2024
Performed by
DJ TUNEZTerry Apala & Musiliu Haruna Ishola
Produced by
DJ TUNEZ & Smeez & Thierry Lohier
Writed by
DJ TUNEZ & Terry Apala & Musiliu Haruna Ishola

Apala Disco (Presidential Remix) Lyrics

[Verse 1]
Egunjọbi Ishola iyi t'Ọba Oluwa fun ẹ ko ni parẹ laye
Ẹ ṣamin ki n gbọ
Ọta kan n binu lasan wọn o le rọna gbe e gba
Ọba to ṣeni n bọ wa ṣọla, a o ni dakobata lawujọ olorin
Amọ ṣa gbogbo ẹni to ba ti ji, to ba sọrọ mi sire
Ire ni ko jẹ ti wọn tori nire nire la a sọrọ atare
Ire ko jẹ ti yin
Ẹ jẹ ko ye yin, gbogbo ẹni to ba ti ji
To sọrọ mi saburu
Emi ma ti fa wọn le Oluwa lọwọ
Ishola nigba kan ri
Ta l'ẹni to so wi pe ko sorin lagodo tiwa, ko si ilu lagodo tiwa?
Irọ lẹ fi pa, eke le fi ṣe ọmọ Egungunjọbi
Awọn temi n complain lojoojumọ Musiliu mi Ishola, DJ Tunez

[Chorus]
O ni ka sọ fun wọn wi pe
O ya gbọti ọlọti lẹ ṣo gbọ?
Gbọti ọlọti lẹ, ṣo gbọ? (Gbọti ọlọti lẹ)
Omu ti ka se apa (Gbọti ọlọti lẹ)
Owo rẹ lom na o (Gbọti ọlọti lẹ)
Mo sọ rẹ to (Gbọti ọlọti lẹ)
Ye wa emu mi (Gbọti ọlọti lẹ)
Ye mu imukumu (Gbọti ọlọti lẹ)
Ye popokupo (Gbọti ọlọti lẹ)
Mo so re to (Gbọti ọlọti lẹ)
Ṣo gbọ? (Gbọti ọlọti lẹ)

[Verse 2]
Egunjọbi, o o ri ọmọge ri, o de fẹ ta si
Ṣẹ ri pipe ọmọge ko ju mẹta lọ
Ta ba fẹ pe ọmọge a maa wi pe, woos, kiskis, hey
Ọlọmọge ti o ba ti dahun o ti kuta niyẹn o
To ba dọjọ alẹ a loun o lori ọkọ

[Bridge]
Ṣo gbọ mi ni?
Terry Apala mo de ni

[Verse 3]
I’m in mood to talk to you
Wetin dey worry you, na me and you
Today na today wey you go know me yeah

[PreChorus]
Ọmọ ẹlẹ nibo lo tun da?
Ko si perfume ka lo lọfinda
Ka ṣe kini yẹn ka yan nọfila
DJ Tunez lori table ka jo goloba
Ọmọ ẹlẹ nibo lo tun da?
Ko si perfume ka lo lọfinda
Ka ṣe kini yẹn ka yan nọfila
We dey cruise ninu party ka jọ maa gbadun

[Chorus]
A maa jaye yii ye yii ye yii
A jọ ma jaye yii
Ṣo gbọ mi ni Terry Apala
A maa jaye yii ye yii ye yii
A jọ ma jaye yii
DJ Tunez lori turntable yeah

[Bridge]
Ko maa lọ beh, ko maa lọ beh, ko maa lọ beh
Ẹ filẹ bẹẹ, ko maa lọ beh
Ẹ jẹ o wa bẹẹ, ko maa lọ beh

[Verse 4]
You call me Bin Ladin
Fun mi rice and salad
DJ Tunez ti sọrọ si
Bread pẹlu sardine yeah yeah
Ṣo gbọ mi ni?
You leave me go meet brother Oseni
Cause I no get money for pocket you leave me
Gbogbo vocabulary ẹnu mi don finish
I’m a bad boy wey no one can defeat
You leave me go meet brother Oseni
Cause I no get money for pocket you leave me
Gbogbo vocabulary ẹnu mi don finish
I’m a bad boy wey no one can defeat
I'm in mood to talk to you
Wetin dey worry you, na me and you
Today na today wey you go know me yeah

[PreChorus]
Ọmọ ẹlẹ nibo lo tun da?
Ko si perfume ka lo lọfinda
Ka ṣe kini yẹn ka yan nọfila
DJ Tunez lori table ka jo goloba
Ọmọ ẹlẹ nibo lo tun da?
Ko si perfume ka lo lọfinda
Ka ṣe kini yẹn ka yan nọfila
We dey cruise ninu party ka jọ maa gbadun

[Chorus]
A maa jaye yii ye yii ye yii
A jọ ma jaye yii
Ṣo gbọ mi ni Terry Apala
A maa jaye yii ye yii ye yii
A jọ ma jaye yii
DJ Tunez lori turntable yeah

[Outro]
Ko maa lọ beh, ko maa lọ beh, ko maa lọ beh
Ẹ filẹ bẹẹ, ko maa lọ beh
Ẹ jẹ o wa bẹẹ, ko maa lọ beh

Apala Disco (Presidential Remix) Q&A

Who wrote Apala Disco (Presidential Remix)'s ?

Apala Disco (Presidential Remix) was written by DJ TUNEZ & Terry Apala & Musiliu Haruna Ishola.

Who produced Apala Disco (Presidential Remix)'s ?

Apala Disco (Presidential Remix) was produced by DJ TUNEZ & Smeez & Thierry Lohier.

When did DJ TUNEZ release Apala Disco (Presidential Remix)?

DJ TUNEZ released Apala Disco (Presidential Remix) on Fri Feb 16 2024.

Your Gateway to High-Quality MP3, FLAC and Lyrics
DownloadMP3FLAC.com