Agogo ati Shekere

Hibeekay

The music player is only available for users with at least 1,000 points.

Download "Agogo ati Shekere"

Agogo ati Shekere by Hibeekay

Release Date
Thu Jul 18 2024
Performed by
Hibeekay
Produced by
Hibeekay
Writed by
Awoyomi Oluwabukunmi Abraham

Agogo ati Shekere Lyrics

#Chorus
Efi duru korin si Oluwa Oba mimo
F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa
K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo
Efi duru korin si Oluwa Oba mimo
F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa
K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo

#Instrumental

#Verse
E korin titun s'Oluwa
Nitori to ti se ohun iyanu
Jeki okun ko ma ho pelu ikun re
Je ki odo ko ma sape k'oke ma sajoyo
E fope f'Oluwa (O seun)
Anu re duro lailai (O seun)
O fi ogbon da orun (O seun)
O te ile lori omi (O seun)
O da awon imole nla (O seun)
Orun lati joba osan (O seun)
Osupa ati irawo joba oru (O seun)
E ba mi f'ope f'Olorun ehh

#Chorus
Efi duru korin si Oluwa Oba mimo
F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa
K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo
Efi duru korin si Oluwa Oba mimo
F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa
K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo

#Verse
Moniwipe
E lo si enu ona re teyin tope
Ati si agbala re teyin tiyin
E dupe e f'ibukun fun oruko re
Nitori to po lore anu re konipekun
Eniti o ranti wa (O seun)
Ninu iwa irele wa (O seun)
Anu re duro lailai (O seun)
O da wa nde lowo ota (O seun)
O fi ounje fun gbogbo eda (O seun)
O sise iyanu nla (O seun)
Jeki gbogbo ohun to lemi (O seun)
Ko fiyin f'Oluwa Oba awon oba

#Chorus
Efi duru korin si Oluwa Oba mimo
F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa
K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo
Efi duru korin si Oluwa Oba mimo
F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa
K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo

#Instrumental

#Chorus
Efi duru korin si Oluwa Oba mimo
F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa
K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo
Efi duru korin si Oluwa Oba mimo
F'ipe ohun fere yin Oluwa Olorun wa
K'agogo ati shekere ko ma ro ke mujojo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo
Eho iho ayo si Oluwa nigba gbogbo

Agogo ati Shekere Q&A

Who wrote Agogo ati Shekere's ?

Agogo ati Shekere was written by Awoyomi Oluwabukunmi Abraham.

Who produced Agogo ati Shekere's ?

Agogo ati Shekere was produced by Hibeekay.

When did Hibeekay release Agogo ati Shekere?

Hibeekay released Agogo ati Shekere on Thu Jul 18 2024.

Your Gateway to High-Quality MP3, FLAC and Lyrics
DownloadMP3FLAC.com